Home iroyin Wahala de! Won ji omo odun meji gbe lo ni soosi
iroyin - October 29, 2017

Wahala de! Won ji omo odun meji gbe lo ni soosi

 

Jinnijinni ti de ba idile kan ni Abuloun, ni Ojo, ni Ipinle Eko bayii.

A gbo pe won ti ji omo won kan to je omo odun meji gbe lo.

Iya omo yii, Iyaafin Anene Jasper, lo ke gbajare  pe nigba ti oun wa ni soosi Anglican Church of Living Faith ni Abulosun ni won ji omo naa gbe, lasiko ti isin n lo lowo.

O war o gbogbo eniyan ki won ran oun lowo, ki won ta oun lolobo bi won ba foju kan omo naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…