Home iroyin Rebecca pa àbúrò bàbá rẹ̀ tó fẹ́ fipá bá a lò
iroyin - October 29, 2017

Rebecca pa àbúrò bàbá rẹ̀ tó fẹ́ fipá bá a lò

Ọdọmọdebinrin ti ko ju ọmọ ọdun mejilelogun lọ ni ọwọ awọn ọlọpaa ipinlẹ Enugu ti tẹ bayii, nitori pe o pa aburo baba rẹ to fẹ fipa baa lo.

Tina Rebecca Sunday ni igba ti arakunrin Friday Mathew to jẹ ọmọ ọdun mejidinlaadọta fọ fi ipa ba oun lo ni oun se fi gbogbo agbara ti i danu ti o si ku.

Ọmọ bibi Ikot Udobang ni Ukanafon to wa ni ipinle Akwa Ibon ni awọn mejeeji. Ohun to ya awọn ọlọpaa lẹnu ju ni bi Tina naa se tẹle arakunrin naa de ile ti wọn ko tii kọ pari.

Iwadii to gbopan si n lọ lọwọ lori isẹlẹ  naa bayii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…