Home LÁGBO ÀRÍYÁ Mo maa n sa fun awon obinrin to ba fe ba mi se isekuse – Akin Lewis
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 29, 2017

Mo maa n sa fun awon obinrin to ba fe ba mi se isekuse – Akin Lewis

 

Agba osere Akin Lewis, ti so pe opo obinrin lo maa n konu si oun pe ki won jo ni ibalopo.

O ni ti o ba je pe gbogbo obinrin to ti konu si oun pe ki won jo ni asepo ni oun ba gba fun ni, boya un kiba ti ku bayii.

O so fun awon oniroyin pe oun ti oun maa n se nip e oun maa n sa danu ti obinrin kan ba ti denu ibasun ko oun.

O ni iyawo oun ni olubadamoron ati ore timotimo oun, to si je pe un kii maa be sita mo bi oun se maa n se tele.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…