Home òpómúléró Leekan sii, Fayose digbo lu Buhari
òpómúléró - October 29, 2017

Leekan sii, Fayose digbo lu Buhari

 

 

Gomina Ipinle Ekiti, Ogbeni Ayodele Fayose, tun ti soko oro si Aare Muhammadu Buhari

O ni eletan lasan bansa ni Buhari, ati pe iro ni ariwo to n pa lori igbogun ti iwa ibaje.

Fayose so pe ti won ba n wa olori jegudujera gan-an, ile Buhari ni ki won lo.

O n oun gan-an ni olori oniwa ibaje.

Bi o tile je pe Fayose ko so idi to fi so oro yii, o ni bi o tile je pe ijoba apapo fe gba owo N321m ti Ogagun Sani Abacha ko pamo si Switzerland, o ni nigba kan ri, Buhari ti fie nu ara e so pe Abacha kii se ole.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…