Home iroyin Owó rẹpẹtẹ jóná mọ mọ́tò Fayose l’Eko
iroyin - October 26, 2017

Owó rẹpẹtẹ jóná mọ mọ́tò Fayose l’Eko

Moto Jiipu boginnin kan lo gbana ni adugbo Osodi ni ipinle Eko. Awon kan ni Olorun lo ko Gomina ipinle Ekiti, Oloye Ayodele Fayose yo ninu ewu ina naa. Won ni bi isele naa se sele ni Fayose sare ko sinu moto miran lara awon ti won jo kọwọọrin.

Awon ti isele naa soju won ni, owo repete ti ilaji re ti jona ni awon direba gomina n sare ko sinu moto miran. Won ni awon owo naa je kikida eedegbeta naira.

Ni igba ti awon oniroyin fi oro wa ogbeni Lere Olayinka lenu wo nipa oro ijamba ina naa, Olayinka ni ki awon oniroyin ma se da awon olote lohun. O ni ko si Gomina ninu moto naa rara. O ni nipa idi naa, oun ko ni le salaye ohun repete to sele ni ibi ijamba naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…