Home iroyin Ọpẹ́ o !Owó epo Malabu wọ Naijiria
iroyin - October 26, 2017

Ọpẹ́ o !Owó epo Malabu wọ Naijiria

Owo rogun-rogun ti awon onijekuje ko sa kuro ni orileede yii ni asiko isejoba Oloogbe Sani Abacha ni die ninu re ti wo orileede Naijiria bayii.

Owo yii ni awon omo Naijiria tun ti n beere wi pe abala ewo ni owo naa ti jade? Nitori pe owo rogun-rogun ti won ji ni asiko naa le ni Oodunrun milionu dola ti o je owo ile okeere.

Bayii, Milionu marunlelogorin dola ($85M) owo ile okeere ni o  wole bayii pelu opolopo wahala ati jija ewe olubori ni awon ile-ejo ile yii ati ti oke okun.

Ibi ti ijoba apapo tun fe na owo naa si tun wa lara ohun ti awon omo Naijiria ni awon fe mo nitori pe ise ati iya si wa ni ilu yii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…