Home LÁGBO ÀRÍYÁ O le ni odun meji ti emi ati Rita Dominic ti soro gbeyin – Jim Iyke
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 25, 2017

O le ni odun meji ti emi ati Rita Dominic ti soro gbeyin – Jim Iyke

?????????????????????????????????????????????????????????
Awon osere fiimu meji kan ti won ti wa timotimo nigba kan ri, Jim Iyke ati Rita Dominic, ko tii ba ara won soro lati nnkan bii odun meji seyin – yala lori foonu ni tabi ni foju-rinju.
Jim Iyke lo so oro yii, nigba to n se arokan lori bi oun ati Rita ti wa tele, ko to di pe ofon-on to si gbegiri, ti onikaluku wa ko eko re lowo.
O ni loooto, aarin awon dan moran tele, sugbon bi awon mejeeji se ri ojo iwaju ko ri bakan naa.
Eyi naa lo fa a ti won ko le fi fe ara won.
O ni Rita Dominic fe ki oun se awon atunto kan lori bi oun se n gbe igbe aye, sugbon eyi ko sele.
Bakan naa, Jim Iyke ni awon mejeeji sese n yo jade bi aseseyo ogomo ni nigba ti awon bere asepo, to si je pe eje omode wa lara awon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…