Home Orisirisi E gbani, e laja, won n ta bata kan ni 15 MILLION DOOLLARS!
Orisirisi - October 25, 2017

E gbani, e laja, won n ta bata kan ni 15 MILLION DOOLLARS!

E wo bata to wa ninu foto yii. Bi e ba fe ra a , elo ni e le san, yala ni naira tabi dola?
E sa ma gbe opobobo naira yin sun mo idi bata naa.
A gbo pe oun ni bata to won julo lagbaaye, ti iye re si je milionu dola meedogun o le die, iyen $15.1m.

Obinrin kan ti oruko re n je Debbie Wingham, to je omo ile Geesi, ni o se bata naa.
A gbo pe goolu ati awon nnkan olowo iyebiye miiran ni won fi se.
Bi bata naa se wa won to, ko ni ya awon eniyan lenu to be je pe omo Naijiria kan lo ra a nigbeyin-gbeyin!

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé

Tinubu kí wọn nílé Akala l’Ogbomọṣọ, ò tún sàbẹ̀wò sí Gómìnà Mákindé Ọrẹ Òtítọ́jù Nítorí à…