Home iroyin E ku ewu o! Benita Okojie bimo lanti-lanti
iroyin - October 23, 2017

E ku ewu o! Benita Okojie bimo lanti-lanti

 

 

Akorin emi to je omode nigba kan, Benita Okojie, ti di iya ikoko bayii.

Oni ojo Monday ni o bimo, ti oun ati oko re, pelu awon ebi won si n dun sinkin.

Ojo bii meji seyin ni Benita gbe foto kan sita nii ti ikun re ti yo bobo.

Ni bayii, Olorun ti pogo, ti a gbo ohun iya, ti a si gbohun omo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…