Home Orisirisi N ko mo okunrin titi ti mo fi pe omo odun mejidinlogbon – Asa
Orisirisi - October 22, 2017

N ko mo okunrin titi ti mo fi pe omo odun mejidinlogbon – Asa

 

Akorin pataki, Bukola Elemde, ti gbogbo aye mo si Asa, ti so pe oun ko mo okunrin kankan ti oun fi pe omo odun mejidinlogbon gbako, iyen 28 years.

Eyi tumo si pe o si wa ni omobinrin digbi, ti ko je ki won jai bale oun titi di asiko naa.

Eyi yoo ya opo eniyan lenu tori omo Eko ni Asa, to je pe Eko lo dagba si, opo si gbagbo pea won omoge Eko, gege bii omoge igboro miiran, saaba maa n je asa.

Won tun gbagbo pe awon omoge ode oni kii le fi ara won pamo, ti opo won si maa n se isekuse kiri.

Bakan naa, awon eniyan miiran a tun wo o pe iru Asa to je akorin, to tun n gbe ni ilu oyinbo, lee je eni ti yoo maa se fokifoki pelu okunrin.

Sugbon ninu iforowanilenuwo kan pelu Funmi Iyanda, sa tenu mo o pe odun bii meje seyin ni won sese mu ododo oun lo – tori omo odun marundinlogoji (35 years) ni bayii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…