Home iroyin Àwọn apẹja rí òkú ẹni tó ròó pin sódò l’Eko
iroyin - October 22, 2017

Àwọn apẹja rí òkú ẹni tó ròó pin sódò l’Eko

Ogbeni Oluseyi Adekunle to wa iwosan ni ilana adura wa si Eko ni o binu ko sodo ni adugbo Lekki si Ikoyi. Orisiirisii nnkan ni awon eniyan ti ro sii bi o se ko somi. Awon kan ni awon aladura eke lo ko si lowo bi o se de lati ipinle Ondo. Awon kan ni ise buruku lo wa se ni Eko lo wa da le e lori.

Yoruba bo, won ni “eni to rajo ti ko tete de lo je ki araye ko ro ibi roo”. Oku lo n jebi ni opo igba, nitori pe ko si akoole idi to fi roo pin sodo, ko tun si laye lati salaye ara re.

Awon apeja lo ri oku yii lori omi ni nnkan bi aago marun-un irole yii, won si ti gbe oku naa fun ijoba ipinle Eko, iwadii si n lo lowo lati le mo “ohun to ri lobe to fi wa owo ro”.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…