Home LÁGBO ÀRÍYÁ Omo kii pe d’agba: Benita naa di aboyunmosu-mamojo!
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 17, 2017

Omo kii pe d’agba: Benita naa di aboyunmosu-mamojo!

 

Omo kii pe d’agba loooto gege bii orin Sikiru Ayinde Barrister. Idi ni pe akorin jojolo tele, Benita Okojie, naa ti di agba, o ti to agbaa da.

Olomobinrin naa to lo sile oko lodun to lo, naa ti di abra meji bayii.

Oro re wad a bii ti Funke Akindele, ti oun naa n be ninu oyun.

Afihan foto Benita kan lori ero alatagba lo taw a lolobo.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…