Home Orisirisi Iyawo mi pariwo nigba ti mo so fun un pe mo fe je Aare Ona Kakanfo – Gani Adams
Orisirisi - October 17, 2017

Iyawo mi pariwo nigba ti mo so fun un pe mo fe je Aare Ona Kakanfo – Gani Adams

 

 

Oga agba ninu egbe Oodua Peoples Congress, Otunba Gani Adams, ti se alaye bi iyawo re, Erelu Mojisola Adams, se koko se nigba ti o so fun un pe oun fe di Aare Ona Kakanfo Yoruba.

Gani Adams so pe eru koko ba obinrin naa, ti o si kigbe too, ati pe o koko yari kanle pe oun ko ni gba ki baale un di Aare Ona Kakanfo.

Sugbon nigba ti Gani Adams salaye fun un, ti oun naa si ri oye pe ise ilu ni baale oun fe se, eru ko ba a mo rara.

Gani Adams lo salaye oro yii lonii, nigba to n baa won oniroyin soro lori ipo Aare to n bo lona.

O ni oun ti gbadura si oye naa gidi, oun ti f’oro lo awon agba, ti won si ni ko ni sewu rara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…