Home òpómúléró Ọmọtọla àti ọkọ rẹ̀ ń seré géle nínú swimming pool!
òpómúléró - October 16, 2017

Ọmọtọla àti ọkọ rẹ̀ ń seré géle nínú swimming pool!

Loooto ife maa n pa awon ololufe bi oti.

Gbajugbaja onifiimu, Omotola, ati baale re, Alagba Ekeinde, ti fi eyi han, nigba ti won jo n we po ninu odo aigbafe alatowoda ti a mo si swimming pool.

Bi won se n doweke ninu omo, ni won n di mo ara won.

Eyi to tun kasiara nibe nip e a ri Alagba Ekeinde nibi ti o ti fi owo fa pata iluwe (swimming suit) ti iyawo re wo, leyii to dabi eni pe o n so fun un pe ara oun wa lona.

Awon mejeeji ko sese maa fi ife won han ninu ile ati lode igba miiran.

Omotola ti maa n so pe Olorun fi oro igbeyawo ke oun tori baale re nifee re pupo, to si wa lara ohun ti o fi ni ilosiwaju gege bii osere ati alariya.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…