Home Orisirisi Gbogbo Yorùbá gbọdọ̀ gbárùkù ti Gani Adams lẹ́yìn gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ tunun – Ayọ Debanjo
Orisirisi - October 16, 2017

Gbogbo Yorùbá gbọdọ̀ gbárùkù ti Gani Adams lẹ́yìn gẹ́gẹ́ bí Ààrẹ tunun – Ayọ Debanjo

 

Agba oselu, Oloye Ayo Adebanjo, ti fi idunnu re han lori bi Alaafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, se fi Otunba Gani Adams je oye Aare Ona Kakanfo tuntun.

Adebanjo ni ojulowo omo Yoruba ni Gani Adams, to si ti ja fun ilosiwaju re.

O ni asiko ti iwosi n gun ile Yoruba yii gan-an ni a nilo Aaare Ona Kakanfo bii ti Gani.

O wa ro retu-t0mo pe ki won se atileyin gidi fun un.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…