Home Orisirisi Fredrick Fasehun kí Gani Adams kú oríire oyè Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò
Orisirisi - October 16, 2017

Fredrick Fasehun kí Gani Adams kú oríire oyè Ààrẹ Ọ̀nà Kakaǹfò

 

Oludasile egbe Oodua Peoples Congress, Dokita Fredrick Fasehun, ti so pe oun ko lodi si bi Alaafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi, se so Otunba Gani Adams di Aare Ona Kakanfo Yoruba.

Fasehun, to je pe oun ati Gani Adams ja lori oro OPC niggba kan, so pe Alaafin letoo lati yan eni to ba wu u , to si je pe ko si ohun to buru bo se yanGani Adams.

O wa ki Gani Adams ku oriire, to si wa sin in ni gbere ipako pe ki o lo ipo naa bo ti to ati bo ti ye.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…