Home iroyin Fayọse fi ọ̀nà tuntun Ikẹrẹ-Ekiti sàyájọ́ ọdún kẹ́ta
iroyin - October 16, 2017

Fayọse fi ọ̀nà tuntun Ikẹrẹ-Ekiti sàyájọ́ ọdún kẹ́ta

Gomina ipinle Ekiti, Oloye Ayodele Fayose pe odun meta lori aleefa, o si fi ona oloda to n yo kuuru se ayeye naa. Ona yi gba ila moto meji ni lilo ati meji miran ni bibo.

Fayose tun dara sii nipa fifi ina to mole rokoso sii, ni eyi to mu ki inu onile ati alejo dun, won si n rojo adura fun gomina naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…