Home iroyin Àwọn agbébọnrìn tún pa àwọn ènìyàn ní Plateau
iroyin - October 16, 2017

Àwọn agbébọnrìn tún pa àwọn ènìyàn ní Plateau

Abule Taagbe to wa ni ijoba ibile Baasa ni awon agbebonrin tun ya bo ni idaji oni ti won si tun bere si ni yinbon lera-lera. Eniyan mefa lo ba isele buruku yii lo ni igba ti opo eniyan si fara pa yonnon-yonnon.

Igba akoko ko niyii ti awon onise ibi maa se iru ise buruku yii, osu to koja naa ni isele bee sele. Awon olopaa ni gbogbo ohun to ba gba ni awon maa fun un lati foju asebi han.

Ose to koja ni awon obinrin ipinle naa se iwode pe ki ijoba apapo ati ti ipinle gba awon lowo awon isele buruku naa, ni eyi ti won ko tile mo pe omiran n bo lonii.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…