Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Messi fẹ̀yìn pọn Argentina lọ World Cup
ERÉ ÌDÁRAYÁ - October 12, 2017

Messi fẹ̀yìn pọn Argentina lọ World Cup

“Eko ko soju mimu” fun iko agbaboolu orileede Argentina ni idije lati lo si ife agbaye to maa waye ni orileede Russia ni odun to n bo. Lati ibere idije naa ni won ti n kuna die-die.

Idije ose yii to waye laarin Argentina ati Ecuador ni o je eyi ti Argentina gbodo jawe olubori daadaa. Ibi idije naa ni gbogbo oju aye wa, nitori pe lati odun 1970, ko si igba ti Argentina kuna lati kopa ninu ife agbaye.

Yoruba bo “won ni ko kin buru titi ki o ma ku enikan mo eniyan, eni to maa ku ni a ko mo”. Eyi lo difa fun orileede Argentina ni ibi idije awon ati orileede Ecuador, opelope elege ara naa, Lionel Messi ni o gbe ise re de to si foba lee nipa gbigba boolu wole alatako re. Eyi lo mu ki Argentina maa pale mo bayii lati lo dije nibi ife agbaya lodun to n bo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…