Home Orisirisi Opo awon omo Senito lo n lo oogun oloro – Ben Bruce
Orisirisi - October 11, 2017

Opo awon omo Senito lo n lo oogun oloro – Ben Bruce

 

Alase ile ise Silverbird Telivision, Alagba Ben Murray-Bruce, ti so pe opo ninu awon omo Senito to wa ni Abuja ni won n lo oogun oloro.

Senito ni Bruce naa, leyii to tumo si pe o nilati o ohun to n sele ninu idile awon eniyan re.

O ni asiko niyi ki awon obi ati alagbato awon omo naa ki won nilo, tori igbeyin oogun oloro kii dara.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…