Home iroyin Ìjọba àpapọ̀ sòfin kò sísẹ́, kò sówó
iroyin - October 11, 2017

Ìjọba àpapọ̀ sòfin kò sísẹ́, kò sówó

Nibi ipade olosoose to maa n waye ni ilu Abuja  ni oro naa ti jeyo lati enu Minisita fun ise, alagba Chris Ngige. O ni loooto ni awon osise letoo si iyanselodi ti won ba ri ohun ti ko te won lorun. O ni bee naa ni ijoba naa ni agbara lati ma se san owo asiko naa fun osise, o ni koda o maa n han ni asiko ti won ba fe feyinti. Gbogbo ojo ti won fi yanse lodi naa ni awon eleto maa yo kuro ninu odun ti won lo.

Ngige ni a ko le maa ba lo bee ki osise yanse lodi fun iye osu meloo kan ki won tun pada de, ki won si gba owo osu ise ti wo ko se. O ni ara igbogun ti iwa ibaje ti awon n so naa ni ki eniyan maa je nibi ti ko ti se.

Minisita yii fi kun un pe ohun to faa ti ise aladaani fi maaa n gboke ju ti ijoba lo naa niyen. O ni ko si aladaani to le gba iru igbakugba ti awoa ara ilu maa n fi lo ijoba.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…