Home ERÉ ÌDÁRAYÁ Eré Bọ́ọ̀lù dùn ún wò, kò dùn ún gbá
ERÉ ÌDÁRAYÁ - October 8, 2017

Eré Bọ́ọ̀lù dùn ún wò, kò dùn ún gbá

Gbogbo eniyan lo feran ere boolu ni wiwo. Opo wa lo si maa n benu ate lu awon ti ko ba gba boolu daadaa ninu ere idije, bẹẹ gẹlẹ si tun ni owo ibi bọọlu naa maa n wọ gbogbo wa loju.

Awọn to mọ bọọlu gba maa n sọọ ni ọpọ igba pe “ita ni ẹni to mọ bọọlu gba wa ju”. Ti agbaboolu kan ba se asise, a maa pe ni orisii orukọ buruku bii ọ̀dẹ̀, òpè, mùmú òpònú ati bẹẹ bẹẹ lọ. A maa sọ pe, koda mama agba wa to wa labule maa gba ọpọ bọọlu ti wọn sọnu wọ inu ile alatako.

E wo fidio bọọlu ọlọrẹẹ-sọrẹẹ isalẹ yii bo se n yọkun nimu agbalagba…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…