Home iroyin Àrùn “Monkeypox”
iroyin - October 8, 2017

Àrùn “Monkeypox”

Orisiirisii arun lo n wo ile aye bayii latari awon nnkan ti a n je ati eyi ti a n mu. Arun “monkeypox” to tun lale wu ni ipinle Bayelsa ati agbegbe re.

Iwadii awon onimo ilera ni pe lati ara “eran igbe” jije paapaa julo obo. Won ni oku ati aaye obo ni ki a sa fun bayii. Won ni ki a kun fun imototo to po gan-an, ki a si din owo-bibo ku. Apeere awon to ti ni arun naa ree…

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…