Home Orisirisi World Cup straight! Alex Iwobi fun Naijiria ni goolu nla!
Orisirisi - October 7, 2017

World Cup straight! Alex Iwobi fun Naijiria ni goolu nla!

 

Erongba Naijiria lati kale si Russia lodun to n bo fun World Cup ti doooto bayii o.

Alex Iwobi ni o mu oriire naa waye, nigba to gba boolu sinu awon Zambia, leyin ti awon egbe agbaboolu naa ti ja fitafita.

Oni kii se ojo gidi fun Odion Igfhalo ati Victor Moses, tori gbogbo anfaani ti won ni to ye ki won fig be boolu s’awon Zambia ni won se ni isekuse.

Sugbon ohun to se koko ju nip e Super Eagles ti ri tikeeti fun World Cup.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…