Home Orisirisi Mercy Aigbe gbase olopaa
Orisirisi - October 6, 2017

Mercy Aigbe gbase olopaa

O jo pe osere fiimu, Mercy Aigbe, ti wa di askari to moje bayii o.

Ara to n da ninu foto yii lo je ki awon eniyan maa ro bee.

Ti a ko ba ni paro, ti a ko ni s’eke, aso olopaa naa ye e.

Sugbon sa o, Mercy ko darapo pelu awon Nigeria Police.

Dipo bee, inu fiimu kan to n po lowo, iyen 77 BULLETS, lo ti kopa gege bii olopaa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…