Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ewo ni obinrin to bimo fun Davido tun n dan wo yi o?
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 6, 2017

Ewo ni obinrin to bimo fun Davido tun n dan wo yi o?

Foto kan ti Sophia Momodu, obinrin to koko bimo fun Davido, ju sori afefe ti n mu ki awon kan maa wuko bayi o.

Foto naa ni awon oloyinbo n pe ni oni-bikinni, ninu eyi to ti wo aso ‘Let them say’ kan.

Sugbon a gbo pe legbe omi, nibi ti oun ati omo re ti lo we, nibi to gbafe lo lorile-ede Georgia, lo ti ya foto naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…