Home Orisirisi Esu to n run lori Argentina ko gbodo run lori Super Eagles!
Orisirisi - October 6, 2017

Esu to n run lori Argentina ko gbodo run lori Super Eagles!

Bee ni. Esu nla n run lori egbe agbaboolu ile Argentina bayii. Pelu bo se je pea won ni won ni agbaboolu to gbona julo lagaaye, iyen Lionel Messi, boya ni won yoo se kopa ninu idije fun ife agbaye World Cup to n bo ni Russia.

Won ko se daadaa rara ninu askagba to n lo lowo.

Omo ayo ti won tun sese ta pelu Peru lo tun wad a wahala si won lagbada, to fogi mo won lori womuwomu.

Sugbon esu to n run lori won yii ko gbodo run lori Super Eagles o.

Idije ti won ni pelu Zambia lojo Satide se pataki gidi ni.

Bi Super Eagles ba le na Zambia, o je pe ka yan falala-falala wo Russia niyen. Koda bi a bat a omi, a ti de ile ileri naa.

Bi a ko ba wa ri okan kan se ninu mejeeji yii, o je pe esu to n run lori Argentina …

 

 

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…