Home Orisirisi Charly Boy gbe awon olopaa lo sile ejo
Orisirisi - October 4, 2017

Charly Boy gbe awon olopaa lo sile ejo

Akorin ati ajajagbara Charly Boy ti gbe olu ileese olopaa Naijiria lo si ile ejo.

O gbe won lo sibe, to si n beere eedegberun milionu naira, iyen N500 million owo gba ma biinu, lori bi won se da oun at awon ti awon jo se iwode risarisa, lasiko ti won so pe o di dandan ki Aare Muhammadu Buhari pada wale lati London, nibi to ti bgba iwosan.

Charly Boy tun fe ki ile ejo pa a lase fun awon olopaa pe won ko gbodo da eni kankan to ba n se iwode laamu mo.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…