Home LÁGBO ÀRÍYÁ Yegede! Taiwo Aromokun bi ibeji leekan sii
LÁGBO ÀRÍYÁ - October 4, 2017

Yegede! Taiwo Aromokun bi ibeji leekan sii

 

Sinkin ni inu osere fiimu, Taiwo Aromokun, n dun bayii, tori Olorun sese yonda ibeji lanti-lanti miiran fun un ni.

Bee, eekeji ti yoo bi ibeji niyi.

O soro idunnu lori isele ayo naa.

O ni oun dupe lowo Olorun to ka oun ye nipa fifi awon ibeji naa da oun lola leekan sii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…