Home iroyin Zahra omo Buhari ke gbajare lori ile iwosan to wa ni Aso Rock
iroyin - September 29, 2017

Zahra omo Buhari ke gbajare lori ile iwosan to wa ni Aso Rock

 

 

Omo Aare Muhammadu Buhari, Zahra, ti figbe ta pe bii agba ofifo ni ile iwosan Aso Rock clinic, to wa ni ile ijoba ni Abuja.

O ni awon osise ibe ko ri irin ise gidi kankan lo. Bee, owo to to bilionu meta naira ni won pin fun ile iwosan naa ninu bojeeti odun yii.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…