Home iroyin Timaya fa Eedris Abdukareem ya yannayanna, o ni amugbo lasan ni
iroyin - September 29, 2017

Timaya fa Eedris Abdukareem ya yannayanna, o ni amugbo lasan ni

Akorin hip hop, Timaya, ti so oro wabiwosi si Eedris Abdukareem, akorin raapu to ko NIGERIA JAGAJAGA.

Timaya ni agba ofifo lasan, ope eniyan ati amugbo lasan-lasan ni Eedris.

O so eyi ni ifesi si oro kan ti Eedris so pe alaimoore ni Timaya.

Eedris ni oun loun fun un ni iwuri ati igboya nigba to sese bere ise orin. O ni sugbon Timaya ko moore.

Eyi lo bi Timaya ninu to fi ni ko gbenu re sinu salanga.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…