Home Orisirisi Oro Daniel Adenimokan ti kuro l’okan mi patapata – Doris Simeon.
Orisirisi - September 27, 2017

Oro Daniel Adenimokan ti kuro l’okan mi patapata – Doris Simeon.

 

Osere fiimu ti a mo si Doris Simeon ti so pe okan ati oju oun ti kuro lara baale re tele, Daniel Adenimokan, patapata.

Oun ati okunrin naa ni won fe ara won tele, to si bi omo kan fun un ko to di pe okunrin naa ja a sile, to sib a Stella Damasus lo.

Doris Simeon ti da wa lati nnkan bii odun mefa ti oro naa ti sele.

O ti wa so fun awon oniroyin pe oun ati Daniel ko tii pinya nilana ti ofin, nitori awon ko tii lo si kootu lati gba iwe ituka ti a mo si divorce.

O wa fi kun un pe, sibesibe, emi oun ti kuro lodo okunrin naa, ti oun ko tile ro oro re mo rara.

O ni odo Olorun ni okan oun wa bayii.

O ni oun ni ololufe pataki kan, sugbon oun ko tii setan lati so nipa re.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…