Home iroyin E wo o bi Oshiomhole se n ba iyawo ati aja re sere!
iroyin - September 27, 2017

E wo o bi Oshiomhole se n ba iyawo ati aja re sere!

 

Lati igba ti Gomina Ipinle Edo tele, Alagba Adams Oshiomhole, ti kuro ni ipo, a ko tii mo ise kan pato to n se. Ko sit ii gba ipo miiran.

Boya eyi lo fun un laaye lati maa je igbadun falala-falala.

Apere iru igbadun bee ni a ri ninu foto yii, nibi ti oun ati iyawo re, Iara, ati aja won ti jo n gbafe.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…