Home iroyin Baba agba di eni awati!
iroyin - September 26, 2017

Baba agba di eni awati!

 

Okan lara awon omo baba ti foto re wa nibi yii ti so pe o ti le ni osu kan ti awon ko ti ri i nile mo.

Ilu Badagry ni baba naa n gbe, ibe lo si ti di eni ti won n wa lati ojo kokandinlogun osu kejo.

A gbo pe o ni oun fe lo se abewo si ore oun kan ni Olodi Apapa ni pinle Eko lojo naa ni.

Won wa ro eni to ba ri baba naa  ko pe nomba yii, 08039248216.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…