Home iroyin Ladoja lòdì sí ìkọlù ààfin Olúbàdàn
iroyin - September 25, 2017

Ladoja lòdì sí ìkọlù ààfin Olúbàdàn

Gomina tele ri ni ipinle Oyo, Oloye Rasheed Ladoja benu ate lu ikolu to waye ni aaro oni laafin Olubadan. O ni ile Yoruba o ki n se onijagidi-jagan. O ni ti ohun ti olubadan ba n se ko ba te awon eda kan lorun, ko ba dara ki iru eni bee gba ile ejo lo.

Ladoja ni nnkan buruku ti ko dara rara ni ki a maa seru ba ara wa. O ni inu oun ati awon ara ilu maa dun ti awon agbofinro ba le fi owo sinkun ofin mu awon onise ibi naa.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…