Home iroyin Buhari tàjò dé
iroyin - September 25, 2017

Buhari tàjò dé

Ipade agbaaye ti Aare Mohammadu Buhari lo ni ose to koja lo ti pari bayii. Ibi ipade naa ni Aare ti raaye gbe awon isoro Naijiria le awon alagbara aye lowo. Ibe naa ni awon ajo agbaaye naa ti n fi n da Aare Buhari ati awon orileede to ku loju pe, awon maa sa gbogbo agbara awon lati se gbogbo iranlowo to ba ye fun ilu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…