Home Orisirisi Wuraola, ìyàwó Ọ̀ọ̀ni tẹ́lẹ̀,  dá awuyewuye míràn sílẹ̀!
Orisirisi - September 24, 2017

Wuraola, ìyàwó Ọ̀ọ̀ni tẹ́lẹ̀,  dá awuyewuye míràn sílẹ̀!

 

Leyin bii ose meji ti awon obi Iyaafin Zainab Otiti, ti a mo si Olori Wuraola Ogunwusi tele, da owo ori ti won gba lowo Ooni pada fun Kabiyesi, obinrin naa tun ti ti da awuyewuye miiran sile o.

Akude to wo igbeyawo Ooni ati Wuraola da opo aroye sile, to si je pe Olorun sese n doola re ni.

Lati fihan pe igbeyawo ti pari loooto, awon ebi Zainab ti da awon nnkan ti Kabiyesi fi dana obinrin naa pada.

Sugbon bayii, awuyewuye miiran si n ja rainpaapaa lori ero alatagba.

Ohun to fa eyi ni pe Iyaafin Zainab si n pe ara re ni ‘Olori’ ati eni nla lori ite oba, iyen Her Royal Majesty.

Opo eniyan n so pe niwon igba ti o ti kuro laafin Ooni, ko ye ko tun ma ape ara re bee mo.

Sugbon awon kan so pe ko si aburu ninu ohun to se.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…