Home Orisirisi Owo olopaa te Jamiu to n se alagbata foonu fun awon ONE CHANCE
Orisirisi - September 24, 2017

Owo olopaa te Jamiu to n se alagbata foonu fun awon ONE CHANCE

 

Bi e ba fe ra foonu aloku, ti won so fun yin pe lati London ni won ti ko o wa, e maa kiye sara o.

Ohun ti arakunrin kan, Jamiu Afolabi, maa n so fun awon eniyan to n ba a ra oja ni eyi.

Sugbon, asiri ti tu bayi.

Awon olopaa ti gba okunrin naa to fi Eko se ibujokoo mu, won ni foonu ole lo n ta.

Owo awon ole to n ji foonu ati awon alagbeda ONE CHANCE ni won ni o ti maa n ra awon foonu naa.

Jamiu se alaye pe loooto ni oun maa n ra awon foonu naa lowo awon jaguda.

O ni awon okunrin kan to n je Uche, Alabi ati Phinero lo maa n ta awon foonu naa fun oun.

Alukoro awon olopaa ni Ipinle Eko, Olarinde Famous Cole, ni awon ti taari keesi naa si ibi to ye.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…