Home iroyin Ori ibeji da seria fun gbomogbomo
iroyin - September 24, 2017

Ori ibeji da seria fun gbomogbomo

 

 

Ase loooto ni ori ibeji le! Ori ibeji ti da seria fun omobinrin kan ni adugbo Alagbado ni Ipinle Eko, lasiko ti o fe ji omo kan to je ibeji gbe salo.

Nigba ti awon araalu gba a mu, won na a bi ejo aije, ti won sig be taya ko o lorun.

Ohun ti Olorun fi yo o ni dide ti awon olopaa de si asiko naa, ti won ko si je ki won sun un guagua.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…