Home iroyin Okiki sa danu leyin to lu alaboyun pa
iroyin - September 24, 2017

Okiki sa danu leyin to lu alaboyun pa

 

Awon olopaa n wa okunrin kan ti oruko re n je Okiki Arisekola, leyin to lu ololufe re tele, Islamat, pa ni adugbo Adekunlke, Yaba, ni ilu Eko.

A gbo pe Islamat ti bi omo kan fun Okiki ki ede aiyede to be sile laarin won.

Eyin eyi ni obinrin naa loyun fun okunrin miiran.

Ede aiyede miiran tun wa be sile lori ibo ni omo to wa laarin Okiki ati Islamat yoo duro si, to si je pe ibe ni Okiki ti fi ibinu ran alaboyun naa lo si orun osan gangan.

A gbo pe ise direba oko igboro ni Okiki n se.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…