Home iroyin Ile ejo tu igbeyawo Onigbinde ka
iroyin - September 21, 2017

Ile ejo tu igbeyawo Onigbinde ka

Adegboyega Onigbinde ka

Ile ejo ti kan ni Mapo, Ibadan, ti tu igbeyawo adari Super Eagles tele, Oloye Adegboyega Onigbinde, ka.

Eni odun kan din logorin (79 years) ni Onigbinde, ti o si je pe ogbon odunseyin ni won ti se igbeyawo naa.

Funra Onigbinde lo gbe obinrin naa ti oruko re n je Anne lo si ile ejo, to si ka awon esun kan sii lese.

Onigbinde ni onijagidijagan eniyan ni Anne, ati pe o maa n ba oun na owo oun ni inakunaa.

 

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…