Home Orisirisi Ija Olubadan ati Ajimobi gba ibomiran yo: Oba Adetunji gbe gomina lo si kootu
Orisirisi - September 21, 2017

Ija Olubadan ati Ajimobi gba ibomiran yo: Oba Adetunji gbe gomina lo si kootu

Olubadan ti Ibadan, Oba Saliu Adetunji ti wa fihan kedere bayii pe oun kii se eye tii ke lojo ti kii ke leerun o.

O si ti fihan pe oun setan lati ba Gomina Abiola Ajimobi na a tan bi owo, iyen fifi awon eniyan mokanlelogun miiran je oba.

Olubadan se eyi nipa gbigbe gomina lo si kootu ni Ibadan.

Awon amoye ni ejo naa yoo je okan gbogi tori opo eniyan ni yoo fe mo ibi ti igi yoo wo si.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…