Home iroyin Paga! Adeyanju ba omo bibi inu re sun leemeje
iroyin - September 20, 2017

Paga! Adeyanju ba omo bibi inu re sun leemeje

 

 

Okunrin laabi kan ti oruko re n je Adeyanju Basiri ti so pe o ti to eemeje ti oun ti ba omo re obinrin lopo.

Omo odun meje si ni omo naa.

Adeyanju pelu babalawo kan ni won jo ledi apo po, ti won fe fi omo naa soogun owo.

Sugbon owo olopaa ti te e, to si ti foju ba  ile ejo.  Pelu ibinu ni adajo se ni ki won sa Adeyanju mo atimole, bi o tile je pe babalawo naa ti salo.

Oga olopaa to n seto keesi naa, Iyaafin Monica Ikebulo, so fun ile ejo pe ojo kokanla osu kesan-an odun yii ni Adeyanju huwa ibaje naa.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…