Home Orisirisi O se, agunbaniro ku iku ojiji!
Orisirisi - September 20, 2017

O se, agunbaniro ku iku ojiji!

 

Okan lara awon agunbaniro to n sise sin Naijiria tun ti ku iku ojiji o.

Arakunrin naa, ti oruko re n je Kenechukwu Ejike Kennedy ni a gbo pe o dede subu lule ni ilu Maiduguri, nibi ti won pin in si.

A gbo pe ibi to subu si naa lo ku si.

Oni ni won gbe oku re lo si ilu re ni Enugu, nibi ti won ti bo o mole, ki Olorun ba wa da owo iru re ro, ko si tu awon obi re ninu.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…