Home iroyin Kò sí ààyè fún ìwà ọ̀daràn mọ́ l‘Eko – Komisona Olopaa
iroyin - September 20, 2017

Kò sí ààyè fún ìwà ọ̀daràn mọ́ l‘Eko – Komisona Olopaa

Komisona tuntun ni ipinle Eko, ogbeni Imohinmi Edgar lo n ba awon oniroyin soro ni ipinle Eko pe, “ki eku ile gbo, ko so fun ti oko, ki adan gbo ko ro fun oobe”. O ni ko le si aaye fun iwa ajinigbe, ole jija ati awon iwa daluru mo ni ipinle Eko.

Oga Olopaa ni gbogbo awon ile-iwe ti won ko si ni aarin ilu, awon to wa ni eti omi tabi eyin odi ilu pata ni awon maa ko awon eso si fun aabo to peye.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…