Home Orisirisi FIFA bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí Chelsea
Orisirisi - September 20, 2017

FIFA bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí Chelsea

Egbe agbaboolu gbaju-gbaja Chelsea ni awon ajo to n dari boolu lagbaye ti bere si ni tona iwadii si ajo naa. Won ni iwe enini kan de odo awon nipa pe egbe agbaboolu Chelsea ra agbaboolu ti ko tii pe odun mejidinlogun, ni eyi to si lodi si ofin ti won fi da FIFA sile.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…