Home iroyin Fayose ní kí ìjọba APC dẹ agbára wọn díẹ̀
iroyin - September 19, 2017

Fayose ní kí ìjọba APC dẹ agbára wọn díẹ̀

Gomina ipinle Ekiti, ogbeni Ayodele Fayose ni o n ba awon oniroyin soro ni ipinle Ekiti ni oni. O ni ki ijoba APC de agbara die, o ni ijoba awa-ara-wa yato pata-pata si ijoba ologun.

Fayose ni ti egbe alatako ba soro won a ni o so oro ikorira tabi ki won ni eni naa fe gba ijoba. O ni ki won ma se gbagbe pe won ko ni wa lori aleefa titi aye. O ni bi ijoba kan se n lo ni ijoba kan n bo.

Gomina Fayose wa ro won ki won jowo maa teti gbo oro tabi aba egbe alatako nitori pe gbogbo wa jo ni ilu ni.

 

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…