Home iroyin ASUU padà sẹ́nu iṣẹ́ pẹ̀lú àdéhùn
iroyin - September 19, 2017

ASUU padà sẹ́nu iṣẹ́ pẹ̀lú àdéhùn

Ajo awon oluko Fasiti (ASUU) ti won ti yan ise lodi lati osu kan seyin bayii ni ijoba ti be ki won pada si enu ise nitori awon omo wa. Ajo naa koko yari kanle pe ijoba apapo ko sese maa tan won sugbon ni igba ti itowo bowe wa ninu adehun naa lo ba mu ki awon ajo naa pada si enu ise ni oni.

Aare ajo naa si fi kun un ninu oro re pe ti ijoba apapo ba ko lati mu adehun re se titi di ipari osu kewaa odun yii, awon maa pada yan ise naa lodi ti awon ko si ni gbebe mo titi ti gbogbo ohun ti awon n beere fun fi maa te awon lowo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…