Home LÁGBO ÀRÍYÁ Ti mo ba t’aye wa, iwo naa ni maa fi se’yawo – Femi Adebayo so fun Omotayo
LÁGBO ÀRÍYÁ - September 18, 2017

Ti mo ba t’aye wa, iwo naa ni maa fi se’yawo – Femi Adebayo so fun Omotayo

Osere fiimu, Femi Adebayo, ti so fun iyawo re, Omotayo Adebayo, pe bi oun ba pada waye leemewa, obinrin naa ni oun yoo fi se aya o.

Ife obinrin naa ti de Femi mole, to si n pa a bi oti.

Lasiko ti o n ki arabinrin naa ku oriire ojo ibi re, Femi ni o ti mu idunnu ati ayo wonu aye oun.

Idi niyi to fi n ki i ni ‘Aduke’ mesan-an, mewaa.

O ni o sese wa ye oun wi pe suuru ti oun ni ki oun to se alabapade Omotayo ko ja s’ofo.

Osere fiimu naa ti koko ni iyawo kan tele, ti igbeyawo naa si f’ori sanpon.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…