Home Orisirisi Ewo ni Liz Anjorin tun n dan wo yi o? Ahon re gbona lala!
Orisirisi - September 18, 2017

Ewo ni Liz Anjorin tun n dan wo yi o? Ahon re gbona lala!

 

Leyin ose die ti onifiimu Liz Anjorin ti Mecca de, o tun ti bere sii dan mewaa wo o.

Foto kan to gbe jade je eyi to gbona lala, nibi to ti yo ahon re jade, lona to le maa mu ki awon okunrin maa d’ofun tolo.

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Check Also

Ó yẹ kí INEC tọrọ àforíjì lọ́wọ́ ọmọ Nàìjíríà – Oshiomole

Asiko ti olori ajo INEC n ba awon oniroyin ati gbogbo elegbejegbe ati ologbajogba ni ilu A…